Awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun ni wọn loo yinbọn pa Bonso
Ochendo lagbegbe Obosi nipinlẹ Anambra lasiko to fẹ ẹ wọ inu mọto ẹ.
Lẹsẹkẹsẹ la gbọ pe Ochendo ti fi aye silẹ.
Awọn ọlọpaa la gbọ pe wọn wa a palẹmọ oku ẹ lọ si
mọṣuari.
NIPA IROYIN AWIKONKO
No comments:
Post a Comment