GOMINA FAYẸMI BAWỌN AGBAAGBA AJỌ ṢỌỌṢI KATOLIIKI YA FỌTO L’ABUJA - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Saturday, February 2, 2019

GOMINA FAYẸMI BAWỌN AGBAAGBA AJỌ ṢỌỌṢI KATOLIIKI YA FỌTO L’ABUJA

Folukẹ Aduragbemi, Ọṣun

Wọnyi ni fọto tawọn agbaagba ajọ ṣọọṣi Katoliiti, iyẹn, Catholic ba Gomina ipinle Ekiti ya lọjọ Fraide ana.

Lara awọn to wa ninu fọto yi ni akọwe fun Catholic Caritas Foundation of Nigeria (CCFN), Rev. Fr. Dr. Uche Obodochina; Biṣọọbu agba ti ẹka ṣọọṣi Catholic nipinlẹ Ṣokoto, to tun jẹ oludasilẹ Kukah Centre, Bishop Matthew Hassan Kukah; Gomina ipinlẹ Ekiti, Dọkita Kayde Faymi.

Awọn min in ni alaga lapapọ fun ajọ CCFN, Archbishop Matthew Ndagoso; alaga lapapọ tẹlẹ fẹgbẹ oṣelu APC, Oloye John Odigie Oyegun; atawọn min in to kopa nibi eto ti wọn pe ni “The Vademecum”, eyi ti wọn fi lelẹ niluu Abuja


No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI