INEC WỌGILE IBO 21,674 NINU IBO AARẸ NI ṢURULERE NIKAN L‘EKO - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, February 25, 2019

INEC WỌGILE IBO 21,674 NINU IBO AARẸ NI ṢURULERE NIKAN L‘EKO

O le ni ibo ẹgbẹrun lọna mọkanlelogun ti ajọ INEC wọgile ladugbo Surulere nikan nipinlẹ Eko.

Nigba to n ka esi ibo aarẹ ti wọn di lọjọ Satide nijọba ibilẹ Surulere, asoju ajọ Inec to se akoso ibo nibẹ salaye pe, rogbodiyan to waye ati bi wọn se n ji apoti ibo gbe, lo jẹ ki iye ibo ti wọn wọgile fi pọ to bẹẹ.

Lẹyin o rẹyin, ni wọn kede ibo aarẹ lati mọ iye ibo ti Atiku Abubakar tẹgbẹ oselu PDP ati Muhammadu Buhari ti ẹgbẹ APC ni.

PDP: 31,603
APC: 30,621

Ibo ti wọn gba wọle: 65784
Ibo ti wọn danu: 4904
 Apapọ iye ibo ti wọn di: 70688
- BBC

Awọn ibo ti wọn danu


No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI