Ẹ WO BAALE ILE TO KU SORI ALE NILUU ABẸOKUTA - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, February 25, 2019

Ẹ WO BAALE ILE TO KU SORI ALE NILUU ABẸOKUTA

Lọsẹ to kọja niroyin naa gba igboro kan pe Baale ile kan ku sori ale ẹ niluu Abẹokuta, ti ko si sẹni to gbe fọto naa jade, ni bayii, lẹyin ọpọlọpọ iwadii, a ṣakiyesi pe ibiṣẹ ni Baale ile naa, Ọgbẹni Abiọdun Aṣimiu dagbere nile fun iyawo atawọn ọmọ ẹ.

O wun wa lati mu ẹkunrẹrẹ iroyin naa wa fun un yi, ṣugbọn latari ẹbẹ to pọ, a ko ni le muu wa

Ẹ ka iroyin ti tẹlẹ nibi: ABIỌDUN LU MAGUN LARA IYA ARUGBO L'ABẸOKUTA


No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI