ỌWỌ EFCC TẸ AWỌN ỌMỌ YAHOO MẸẸDOGUN N'IBADAN PẸLU PATA OBINRIN ATI ỌṢẸ DUDU LORIṢIRIṢI - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Friday, February 1, 2019

ỌWỌ EFCC TẸ AWỌN ỌMỌ YAHOO MẸẸDOGUN N'IBADAN PẸLU PATA OBINRIN ATI ỌṢẸ DUDU LORIṢIRIṢI

Ọla Eyitayọ, Ọyọ

Iyalẹnu lọrọ awọn ọmọ Yahoo tọwọ awọn ajọ EFCC tẹ laipẹ yi niluu Ibadan latari bi wọn ṣe ba oriṣiriṣi oogun abẹnugọngọ, ọṣẹ dudu atawọn mọto bọginni-bọginni.EFCC busts 19 yahoo boys

Agbegbe Ologunẹru ati Akobọ nillu Ibadan la gbọ pe ọwọ ti tẹ awọn mọkandinlogun naa.
 
EFCC busts 19 yahoo boys

Awọn naa ni Bamidele Ayọdele Samson, Bamidele Philip, Tunji Ọladapọ Ṣowale, Bọlaji Ọlalekan, Abdulrauf Abiọdun, Ọlalẹyẹ Pẹlumi, Anuoluwapọ Ọlanrewaju, Paul Damilọla, Ọlalẹyẹ David Tobi, Arẹwa Adekunle Ibrahim, Oyesanmi Ayọmikun Oluwaṣeun, Ọlalẹyẹ Israel, Adediran Kemisọla, Ọmọbọlade Alarape ati Olowolusi Oluwatomisin.


Awọn to ku ni Babatunde Afeez, Akorede Ahmed Ọlalekan, Adelẹyẹ Damilọla ati Moshood Richard.

EFCC busts 19 yahoo boys


AWIKONKO gbọ pe laarin ọdun mọkanlelogun si ọdun marundinlogoji lawọn gendekunrin naa tọwọ tẹ yi, akẹkọọ wa lara wọn bẹẹ lawọn kan ti jade ile ẹkọ.EFCC busts 19 yahoo boys


EFCC busts 19 yahoo boys
No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI