ṢINA PELLER DI AṢOJU-ṢOFIN TUNTUN NILUU ỌYỌ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, February 25, 2019

ṢINA PELLER DI AṢOJU-ṢOFIN TUNTUN NILUU ỌYỌ

Shina Peller , tii se gbajugbaja amuludun kan nilu Eko, ti wọle sile asoju-sofin lẹkun idibo Isẹyin/Itẹsiwaju/Iwajọ̀wa nipinlẹ Ọyọ.

Sina Peller si lo fi ẹyin Najeemdeen Oyedeji tẹgbẹ oselu PDP janlẹ ninu ibo naa.

APC: 44,088

PDP: 31,336

ADC: 12,309

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI