Ẹ FURA O: ỌRILEEDE BENIN NI ỌLAWALE TI N WA FI OWO LU AWỌN ỌMỌ NAIJIRIA NI JIBITI AYEDERU OWO - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Saturday, March 16, 2019

Ẹ FURA O: ỌRILEEDE BENIN NI ỌLAWALE TI N WA FI OWO LU AWỌN ỌMỌ NAIJIRIA NI JIBITI AYEDERU OWO

Kani kii e pe awn oṣiṣẹ ojulalakanfinsori, iyn Fijilante tijba ipinl Ogun, VSO ko sun asunpara ni, bo ya ọwọ wn ko ba ma ti t baale ile ni dun mkanlelaadta (51) kan, lawale Ibrahim ti wn s pe ko niṣẹ min in ju ko maa fi ayederu owo lu awn araalu ni jibiti l.

Gẹgẹ ba a e gb, orileede Benin, iyn Kutnu ni wn s pe lawale ti n ko ayederu owo naa w Naijiria, lati fi lu awn eeyan ni jibiti, ko too tun pada l ko min in wa.

AWIKONKO gb pe ọjọ Tọside ọsẹ to kja lọ lọhun lọwọ palaba lawale ti wn nile Samul, adugbo Baba Pupa, lagbegbe Sm, Badagry niluu Eko lo n gbe. Ilu kan ti wn n pe ni Afuy nitosi Ifnyintdo, Idiroko lọwọ palaba ẹ ti segi ni nnkan bi aago mfa irọlẹ ọjọ naa.

Nigba tọwọ maa tẹ ẹ, ibi to ti n paarọ owo lọwọ lairi ti tu pe ayederu owo lo kun ọwọ ẹ, to si fi n lu awn eeyan ni jibiti. Bairi si e tu lo gbiyanju lati sal ko too ko sọwọ awn oṣiṣẹ Fijilante naa.

" e mi jẹjẹ, maa jw" l'orin ẹbẹ ti wn loo mu snu nigba ti okete ko raaye boru mọ wọn lọwọ, lsks lo jw pe o ti p toun ti wa nidi iṣẹ naa, ati pe oun ni ga kan to n j Luwe, ni to loo fi Kutnu ebugbe.

Nigba to fidi iṣẹlẹ naa mul f'AWIKONKO, alukoro gb fijilante, gbni Mruf Yusuf s pe gbrun kan naira lna mẹọo ati gbrun mwa cefa lna msan an (8 pieces of #1,000 note and 9 pieces of 10,000 cefa) lowo tawn gba lọwọ loju ẹsẹ.

O wa a s pe ga awn, Sji Ganzallo ti paṣẹ pe kawn gbe lawale lo tean ọlọpaa Idiroko lati tsiwaju ninu iwadi wn. Gbogbo akitiyan lati ba alukoro ileeṣẹ ọlọpaa ipinl Ogun, Ọgbẹni Abimbla Oyeymi sọrọ lo ja si pabo dasiko ta a ṣakojp iroyin yi tan.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI