O TAN O: ILE ẸJỌ TRIBUNAL LE GOMINA IPINLẸ ỌṢUN, OYETỌLA DANU - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Friday, March 22, 2019

O TAN O: ILE ẸJỌ TRIBUNAL LE GOMINA IPINLẸ ỌṢUN, OYETỌLA DANU

Ile ẹjọ Tribunal orileede yi to fikalẹ siluu Abuja to n gbọ ẹsun idibo ipinlẹ Ọṣun to waye loṣu kẹsan an ọdun to kọja yi ti sọ pe ayederu ibo ni wọn fi kede ibo to gbe Alaaji Gboyega Oyetọla wọle gẹgẹ bii Gomina ipinlẹ naa.

Oni, tii ṣe Fraide nile ẹjọ paṣẹ pe ki Gomina Oyetọla ti ẹgbẹ oṣelu APC da iwe ẹri to gba lọwọ ajọ eleto idibo, iyẹn INEC pada fun Sẹnetọ Ademọla Adeleke ti ẹgbẹ oṣelu PDP, nitori pe pẹlu awọn eri aridaju, oun gan an lo jawe olubori.

Ẹkunrẹrẹ iroyin naa n bọ lai pẹ.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI