KAYEEFI NLA RE O: GBAJUMỌ BIṢỌỌBU POKUNSO - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Saturday, April 27, 2019

KAYEEFI NLA RE O: GBAJUMỌ BIṢỌỌBU POKUNSO

Iyalẹnu lọwọ Biṣọọbu Richard Bile ṣi n je fun ọpọ awọn eeyan to gbọ latari bo ṣe pokunso lọsan gangan lọjọ Tọside to kọja yi.

A gbọ pe oriṣiriṣi awọn ọmọ kekeeke ni ni Biṣọọbu naa ti ja ibale wọn, to si tun fa wọn nidi ya pẹrẹpẹrẹ, iyẹn lorileede Ivory Coast.

Saaju asiko yi, iyẹn lọjọ Wẹside lawọn agba Pasitọ ninu ṣọọṣi Katoliiki,ẹka ti Saint Francis of Assisi D ‘ Affiénou (Maferé) ti ta a lolobo lori igbesẹ tawọn fẹẹ gbe lati daa duro fungba diẹ. Bo si ṣe gbọ eyi la gbọ pe wọn deede ri oku ẹ nibi to so ara rẹ kọ si.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI