LẸ́YÌN OṢÙ MÁRÙN ÚN, BUHARI KỌ̀ LÁTI YỌ ỌGA NHIS BÍ ÌGBÌMỌ̀ ṢE SỌ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Tuesday, April 16, 2019

LẸ́YÌN OṢÙ MÁRÙN ÚN, BUHARI KỌ̀ LÁTI YỌ ỌGA NHIS BÍ ÌGBÌMỌ̀ ṢE SỌ

Lẹyin ti ina jo ijọ Aguda nla ti orilẹ-ede Faranse ni aarẹ Emmanuel MAcron ti ni oun ṣetan lati tun un kọ.

Macron ni ile ijọsin naa wa lara itan ayanmọ ilẹ Faranse ni eyi ti ẹnikẹni ko le gbagbe.

O n beere fun ifọwọsowọpọ gbobo eniyan Faranse nile ati loke okun ki wọn le jọ yanju ọrọ naa.

Àwọn òṣìṣẹ́ pàjáwìrì ti pa'ná tó jó ìjọ àgùdà tí wọ́n f'igba ọdún kọ́.

Macron fi soju òpó ayelujara rẹ pe, iṣẹ ajumọṣe ni atunṣe ile ijọsin naa yoo jẹ pe, iṣẹ ti de naa ni yẹn lori orirun wọn.

Lọjọ kẹẹdogun, oṣu kẹrin, ọdun 2019 ni iná sọ ni Notre Dame

Awọn oṣiṣe pajawiri ti pa ina to jo ile ijọsin atayedaye Notre-Dame Cathedral to wa ni ilu Paris, orilẹede France, eyi ti ina bọ si ni ọjọ Aje.

Ijọba orilẹede naa ni ko ti si ẹni to le sọ pato oun to fa ina na to ran de awọn apa ibomiiran ninu ọgba rẹ.

Ina naa ba ọpọ awọn to fẹran itan atayedaye ninu jẹ nitori ọjọ ori ile ijọsin naa. Itan sọ fun wa wipe, fun igba ọdun ni wọn fi kọ ile ijọsin Notre-Dame Cathedral ati wipe ọdun aadọtalelẹgbẹrin sẹyin ni wọn ti kọ.

Aarẹ orilẹede France, Emmanuel Macron ti ṣe ileri lati tun ile ijọsin naa ṣe lẹyin ina naa.

Se ni o ta kan de ibi ti ina naa ti n jo lẹyin to fagile eto ọrọ to gbero lati ba awọn ọmọ orilẹ-ede naa sọ lonii.

Ọgbẹni Macro ni "bi gbogbo ọmọ orilẹ-ede mi, inu mi bajẹ lalẹ yii lati ri ibi to n jona yii".

Lọdun to kọja ni ijọ naa ṣe ikowojọ oni pajawiri ni orilẹ-ede France lati wa owo ti wọn yoo fi tun ijọ to ti pe ọdun ẹgbẹjọ o le aadọta naa kọ eyi to ti bẹrẹ si ni da wo.
Media captionÀàrẹ Buhari ti gba Ààrẹ Macron ti orílẹ̀èdè France lálejò nilu Abuja

Awọn oṣiṣẹ pana-pana ti n ṣe iṣ lọ ni pẹrwu lati gbiyanju dida ọwọ ina naa duro.

- BBC YORUBA

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI