EWURẸ LO JI GBE KI WỌN TO DANA SUN-UN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Sunday, May 5, 2019

EWURẸ LO JI GBE KI WỌN TO DANA SUN-UN

Ko sẹni to wa nibi ti wọn ti dana sun ọdọmọkunrin kan ti wọn fẹsun kan pe o lọọ ji ẹran ewurẹ gbe, toun naa yoo gbiyanju lati jale nigbesi aye ẹ.

 
Ilu Aba, nipinlẹ Abia niṣẹlẹ naa ti waye lopin ọsẹ yi.

 
Ohun taa gbọ ni pe ṣe ni wọn de ọkunrin naa, ko too di pe wọn dana sun un nita gbangba.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI