IGBEYAWO KU OṢU MẸTA, ỌKỌ IYAWO LU OLOLUFẸẸ LOJU FỌ DANU - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Sunday, May 12, 2019

IGBEYAWO KU OṢU MẸTA, ỌKỌ IYAWO LU OLOLUFẸẸ LOJU FỌ DANU

Adura tawọn ọdọmọkunrin ati ọdọmọbinrin ti wọn ti kun oju oṣuwọn lati ṣegbeyawo maa n gba ni pe kawọn ma ṣi ọkọ tabi iyawo fẹ, ati pe ki Ọlọrun fun wọn lẹni ti yoo tete gbe ayanmọ wọn lori soke.

Ṣugbọn adura naa ko ri bẹẹ fun awọn ololufẹ meji kan ti wọn ti da ọjọ igbeyawo wọn soju ọna, iyẹn igbeyawo naa ti yoo waye loṣu kẹjọ ọdun yi.

Ori ayelujara ni ọkunrin kan gbe aworan aburo rẹ si, to si n sọ fun gbogbo aye pe ọkọ afẹsọna aburo oun lo luu bayii.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI