ỌDAJU ABIYAMỌ: NIBI IDIJE WAFU, NAIJIRIA ṢE NIGER ṢIBAṢIBO - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Sunday, May 12, 2019

ỌDAJU ABIYAMỌ: NIBI IDIJE WAFU, NAIJIRIA ṢE NIGER ṢIBAṢIBO

Pupọ ninu awọn ti wọn ko mọ ẹgbẹ awọn agbabọọlu Niger lobinrin ni wọn n ba wọn sunkun lalẹ ana Satide, nigba ti ẹgbẹ agbabọọlu awọn obinrin Naijiria, iyẹn Super falcons foju wọn han mabo pẹlu aami ayo mẹẹdogun si oodo.

Abijan ti idije naa ti n waye lọwọ ni ikọ ẹgbẹ agbabọọlu Super Falcons ti kọkọ padanu sọwọ ẹgbẹ agbabọọlu Mali pẹlu aami ayomẹwaa si oodo.

Pẹlu ibinu ni Super falcons fi diju, ti wọn si ko iya malegbagbe bo awọn akẹgbẹ wọn.

Ṣaaju asiko yi ni Super Falcons ti fagba han orileede Burkina Faso pẹlu aami marun si ẹyọkan ṣoṣo.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI