AYAJỌ AWỌN BABA, FUNKẸ AKINDELE GBE OṢUBA KARE FUN ỌKỌ Ẹ, JJC - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉSunday, June 16, 2019

AYAJỌ AWỌN BABA, FUNKẸ AKINDELE GBE OṢUBA KARE FUN ỌKỌ Ẹ, JJC

Adura bayii lawọn ololufẹ gbajugbaja oṣere-binrin nni, Funkẹ Akindele-Bello n gba foun ati ọkọ ẹ JJC lori bo ṣe gbe fọtọ ọkunrin naa sita, to si n ki ku ayẹyẹ ayajọ awọn baba lagbaye.
Yatọ si pe Funkẹ n ọkọ ẹ, o tun gbe fọto ọkunrin naa sita pẹlu awọn ibeji wọn ti wọn bi loṣu kejila ọdun to kọja, tawọn eeyan si n gba a ladura pe wọn yoo lo ara wọn gbo.

No comments:

Post a CommentPÍN-IN KÁÀKIRI