ORIN 'O TO GẸ' NI WỌN N KỌ FUN GOMINA AKEREDOLU BAYI O - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Saturday, June 15, 2019

ORIN 'O TO GẸ' NI WỌN N KỌ FUN GOMINA AKEREDOLU BAYI O

Folukẹ Aduragbemi, Ọṣun

"O TO O GẸ Ẹ, AKETI, Ẹ WA MA A LỌ" ti wọn lawọn ẹgbẹ kan ti wọn pe ara wọn ni Hope of The Masses n kọ bayii nipinlẹ Ondo fun Gomina wọn, Ọgbẹni Rotimi Akeredolu, pe asiko ẹ ti to.

Gẹgẹ b'AWIKONKO ṣe gbọ, wọn ni ọrọ Gomina Akeredolu ti su awọn araalu, ati pe ọkunrin kan ni fẹẹ ṣagbatẹru ẹ ninu idibo ti yoo tun waye lọdun 2020.

Ẹkunrẹrẹ iroyin naa n bọ lai pẹ.
No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI