Inu idunnu ati ayọ lawọn ẹgbẹ agbabọọlu Super Eagles ti orilẹ-ede Naijiria wa bayii pẹluu bi awọn olowo ati ọlọrọ nni, Aliko Dangote ati Fẹmi Ọtẹdọla ṣe ti ṣeleri obitibiti owo fun wọn lori awọn idije to ku yii.
Ẹgbẹrun marundinlọgọrin ($75,000) dọla lowo ti wọn ṣeleri fun wọn lori awọn goolu ti wọn ba gba wọle.
No comments:
Post a Comment