Ẹ WO ẸJA NLA TI WỌN RI NI BAYELSA - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉSunday, August 25, 2019

Ẹ WO ẸJA NLA TI WỌN RI NI BAYELSA


Ọrọ ẹja nla ti wọn ri nipinlẹ Bayelsa ṣi n jẹ kayeefi fawọn eeyan titi dasiko yi. Ẹja naa tobi gidi gan, ko da a, ti wọn loo le gbe odindi eeyan min in.

No comments:

Post a CommentPÍN-IN KÁÀKIRI