MERCY AIGBE BỌ ARA RẸ SIHOHO NITA GBANGBA, LAWỌN EEYAN BA FI N ṢẸLẸYA - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, August 12, 2019

MERCY AIGBE BỌ ARA RẸ SIHOHO NITA GBANGBA, LAWỌN EEYAN BA FI N ṢẸLẸYA

Bo tilẹ jẹ pe ohun tawọn kan n sọ ni pe 'ko jẹ tuntun' lohun tawọn kan n sọ, ṣugbọn sibẹ, iyalẹnu nla lo n jẹ fun ọpọ awọn to ri fọto ihoho ti gbajumọ oṣerebinrin nni, Mercy Aigbe gbe sori ayelujara laipẹ yi n jẹ.

United Kingdom la gbọ pe Mercy Aigbe to kọ ọkọ rẹ silẹ laipẹ yi, nibi to ti n ṣe faaji ara rẹ.

Ile igbafẹ kan la gbọ pe Mercy lọ, to si lọọ wẹ nidi odo iwẹ igbaloode (Swimming Pool) kan lo ti lọọ ṣe faji, to si gbe fọto naa sita fawọn ololufẹ rẹ lati ri bi ihoho ohun ṣe ri.

Awọn to wo fọto naa daadaa ti ẹ sọ pe Mercy n ṣe nnkan oṣu rẹ lọwọ, pẹluu bi kinni ti wọn maa n fi soju ara obinrin lasiko nnkan oṣu ṣe jẹyọ labẹ rẹ.

Bẹẹ lawọn kan n sọ pe kii ṣe awokọṣe rara fawọn obinrin, paapaa awọn iyaale ile.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI