AWỌN ỌDARAN WỌ GAU NIPINLẸ OGUN LẸYIN ỌGỌRUN ỌJỌ TI DAPỌ ABIỌDUN GBA IJỌBA - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Saturday, September 7, 2019

AWỌN ỌDARAN WỌ GAU NIPINLẸ OGUN LẸYIN ỌGỌRUN ỌJỌ TI DAPỌ ABIỌDUN GBA IJỌBA

Image may contain: 4 people, people standing Image may contain: 2 people, people sitting
Ẹsẹ ko gbero ni gbagede awọn ologun to fikalẹ sinu ọgba awọn oṣiṣẹ ati ileeṣẹ Gomina ipinlẹ Ogun to wa ni Oke-Mọsan, Abẹokuta lọjọ Ẹti Fraide ana nigba ti Gomina Dapọ Abiọdun fi mọto ati ọkada ti ko din ni ọọdunrun (300) tọrẹ fawọn ọlọpaa, ki eto aabo le tubọ kẹsẹ jare.

Image may contain: 8 people, people standing 
Ọga Ọlọpaa patapata lorilẹ-ede Naijiria, Mohammed Adamu lo tẹwọ gba awọn eroja ti yoo mu ki iṣẹ aabo rọrun fun ileeṣẹ ọlọpaa nipinlẹ Ogun, lara awọn to si wa nibẹ ni Alake ilẹ Ẹgba, Ọba Adedọtun Gbadebọ; Olu Itori, Ọba Akorede Akamọ; Olu Owode atawọn min in, to fi mọ gbogbo ẹgbẹ onimọtọ ati ọlọkada ati gbogbo awọn ileeṣẹ eleto aabo patapata.

Image may contain: 2 people, indoor Image may contain: 1 person, sitting and car
Image may contain: one or more people, people sitting and closeup
Image may contain: car and outdoor 
Nigba to n sọrọ, Gomina Dapọ Abiọdun sọ pe oriṣiriṣi iwa ọdaran loun ti gbọ latigba toun ti di Gomina, ṣugbọn latari awọn ileri toun ṣe lati ma jẹ ki eto aabo ipinlẹ naa mẹhẹ lasiko ipolongo idibo, ijọba oun yoo pese awọn nnkan idẹrun fun gbogbo ileeṣẹ eleto aabo patapata.

Image may contain: car and outdoor 
Awọn ileeṣẹ eleto aabo bii Immigration, Road Safety, TRACE, FRSC, NSCDC, Vigilante Group of Nigeria, So Safe Corps atawọn min in ni ko gbẹyin nibẹ lọjọ naa.

Image may contain: outdoor 

Diẹ re e lara bi eto naa ṣe lọ si atawọn nnkan ti ijọba fi tọrẹ fun wọn.

Image may contain: outdoor
Image may contain: one or more people and outdoor
Image may contain: outdoor
Image may contain: one or more people and outdoor
Image may contain: one or more people, crowd and outdoor










No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI