BAALE ILE DUNBU AWỌN ỌMỌ RẸ MẸTA BI ẸRAN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


https://haxbyq.com/mario?h=waWQiOjExNDYwMDIsInNpZCI6MTE4NDA4MCwid2lkIjo0MjE1NzYsInNyYyI6Mn0=eyJ&si1=&si2=


Wednesday, December 25, 2019

BAALE ILE DUNBU AWỌN ỌMỌ RẸ MẸTA BI ẸRAN

Ko tii daju pe baale ile kan ti wọn pe orukọ ẹ ni Chinasa Ogbaga ko nii lo eyi to ku n'igbesi aye rẹ lọgba ẹwọn lẹyin ti ile ẹjọ ba daa l'ẹbi wipe o jẹbi awọn ẹsun ti wọn ba fi kan an.

Ọjọ Abamẹta Satide ọsẹ to kọja yi la gbọ pe Chinasa ti wọn l'oṣu keji ọdun yi lo kọ iyawo rẹ ti bi awọn naa fun un ko awọn rẹ jade laarin oru lẹyọ-kọọkan, to si n dunbu wọn bi ẹran ọdun Ileya l'agbegbe Egwuagu Okpuitumo to wa nijọba ibilẹ Abakaliki, ipinlẹ Ebonyi.

Aarọ ọjọ keji tii ṣe ọjọ Aiku Sande lawọn araadugbo too ṣẹṣẹ mọ pe nnkan ti ṣẹlẹ, tia  si gbọ pe ọkan lara awọn ọmọ naa to jẹ ọmọdun meji lori ko yọ, ti wọn si sare gbe e lọ si ọsibituAlex Ekwueme to ti n gba itọju lọwọ.

Awọn ọmọ naa ni: Chikamso Ogbaga, ọmọdun mẹfa; Chizaram Ogbaga, ọmọdun mẹrin ati Emmanuel Ogbaga toun jẹ ọmọdun meji.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI