ATIKU BẸ AWỌN ỌMỌ NAIJIRIA LATI GBADURA FUN ỌMỌ RẸ TO NI CORONAVIRUS - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Monday, March 23, 2020

ATIKU BẸ AWỌN ỌMỌ NAIJIRIA LATI GBADURA FUN ỌMỌ RẸ TO NI CORONAVIRUS

Oludije sipo Aarẹ orilẹ-ede yii l'ọdun to kọja, Alaaji Atiku Abubakar ti rawọ ẹbẹ s'awọn ọmọ Naijiria wi pe ki maa ba oun fi adura ranṣẹ si ọmọ oun to ti ko aarun Coronavirus bayii.

Ori ikanni ayelujara ti Twitter ni Atiku ti sọrọ naa l'ọjọ Aiku, Sannde an, to si ni awọn eleto ilera ti mọ nipa ẹ, ati pe ọsibitu kan Gwagwalada, Abuja ni wọn gbe e lọ fun itọju. 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI