EYII NI BI AYẸYẸ ỌJỌ IBI ỌBASANJỌ ṢE LỌ, ATI BI CORONAVIRUS ṢE DENA AWỌN ALEJO LATI WA - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Friday, March 6, 2020

EYII NI BI AYẸYẸ ỌJỌ IBI ỌBASANJỌ ṢE LỌ, ATI BI CORONAVIRUS ṢE DENA AWỌN ALEJO LATI WA

Bo tilẹ jẹ pe inu Aarẹ orilẹ-ede Naijiria, Oloye Oluṣẹgun Ọbasanjọ ko fi bẹẹ dun pupọ lori ọna ti ayẹyẹ ọjọ ibi ọdun mẹtalelọgọrin rẹ to waye l'ọsẹ yii, sibẹ, orin ọpẹ lo gba ẹnu rẹ kan wi pe oun tun ri ọdun mi-in, tawọn eeyan kaakiri agbaye si n ba a yọ pupọ.

Image may contain: 7 people 
Aarun kan to n ja rain-rain kaakiri agbaye lasiko yii, iyẹn Coronavirus lo fa a ti Oloye Oluṣẹgun Ọbasanjọ ṣe fa ọwọ eto naa sẹyin, nitori pe awọn eeyan jankan-jankan kaakiri agbaye lo yẹ ko wa nibẹ, ṣugbọn itankalẹ aarun naa ko faaye silẹ lati pe ero.

Diẹ re e lara bi eto ayẹyẹ naa ṣe lọ si i n'ilu Abẹokuta:

Image may contain: 2 people, eyeglasses and suit 
Image may contain: one or more people and suit 
Image may contain: 5 people, people standing

Image may contain: one or more people and indoor

Image may contain: 3 people
 Image may contain: 3 people

Image may contain: 1 person, drink

 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI