O GA O! SANWÓ-OLÚ TÚN SỌ̀RỌ̀ LÓRÍ ṢÍṢÍ ILÉ-IJỌSIN L'ÉKÒÓ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Tuesday, June 16, 2020

O GA O! SANWÓ-OLÚ TÚN SỌ̀RỌ̀ LÓRÍ ṢÍṢÍ ILÉ-IJỌSIN L'ÉKÒÓ


Gómìnà Babajide Sanwo-Olu tipinlẹ Èkó tí sọ pé kò tíì tó àsìkò láti ṣí àwọn ilẹ̀kùn ilé ìjọsìn bíi ṣọọṣi àti mọṣalaṣi silẹ, nítorí pé ṣe ni itankalẹ àrùn COVID-19 tún ń pọ̀ sii, kàkà kó dínkù.

Lónìí ní Gómìnà Sanwo-Olu sọ̀rọ̀ náà síta lásìkò tó ń b'awọn oniroyin sọ̀rọ̀ nílé ìjọba tó wà ní Marina. 

Bẹ ó bá gbàgbé, ṣáájú àsìkò yìí ni ìjọba tí kéde pé ọjọ́ kọkàndínlógún àti ọjọ́ kọkanlelogun oṣù yìí ni mọṣalaṣi àti ṣọọṣi yóò silẹkun láti bẹ̀rẹ̀ sii jọsin. 

Ní báyìí, ó ọ̀rọ̀ náà kò níí rí bẹ́ẹ̀ mọ. 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI