ÀWỌN ÀGBẸ̀ KÒKÓ BỌ́ S'AYÉ NÍ KWARA - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, September 10, 2020

ÀWỌN ÀGBẸ̀ KÒKÓ BỌ́ S'AYÉ NÍ KWARA


Ìjọba ìpínlẹ̀ Kwara tí bù ọwọ lu fífún àwọn àgbẹ̀ òní kòkó ni èso kòkó {Cocoa} láti gbìn lásìkò yìí. 

Èso kòkó tí wọn pé ní Hybrid Cocoa Seedlings ni wọn fẹẹ fún gbogbo àwọn àgbẹ̀ káàkiri ìpínlẹ̀ náà, pẹ̀lú erongba láti jẹ ki oúnjẹ pọ lọpọ yanturu. 

Èyí ni lati ran àwọn àgbẹ̀ lọ́wọ́ lórí ajakalẹ àrùn Covid19 tó dojú nnkan ru fáwọn àgbẹ̀. 


Lónìí ní eto naa bẹ̀rẹ̀ n'ilu Ilọrin, ìpínlẹ̀ náà nígbà tí igbá-kejì Gómìnà, Kayọde Alabi pín èso kòkó tí dín ni ẹgbẹ̀rún lọ́nà àádọ́ta fún àwọn àgbẹ̀. 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI