BÀBÁ LẸGBA, ÀGBÁ ÒṢERÉ TÍÁTÀ TI KÚ OOOOOOO - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, September 7, 2020

BÀBÁ LẸGBA, ÀGBÁ ÒṢERÉ TÍÁTÀ TI KÚ OOOOOOO


Ṣé ni ariwo ibanujẹ ńlá mi ín tún sọ lagboole àwọn òṣeré tíátà laaarọ òní ọjọ́ Aje, Mọnde nígbà tí Alagba Yekini Oyedele táwọn èèyàn tún mọ sì Baba Lẹgba jáde láyé.

Baba Lẹgba lọ jáde láyé lẹ́yìn àìsàn rampẹ ni kò pé tó rawọ ẹ̀bẹ̀ sáwọn ẹlẹyinju àánú káàkiri àgbáyé fún àánú àti iranlọwọ

Èyí ni ọ̀rọ̀ tó sọ gbẹyin kò too ku



Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìròyìn náà ń bọ̀ 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI