Gbajugbaja agbabọọlu ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà nnì, tó tún ń gba iwájú fún ẹgbẹ́ agbabọọlu Barcelona, Asisat Oṣhoala lo ṣe abẹwo sì Ọba Saheed Ademọla Kushenla kẹta, ìyẹn Eleguṣhi tilu Ikate n'ilu Eko.
Níbi abẹwo náà ni Asisat tó ti gba oríṣiríṣi àmì ẹyẹ káàkiri àgbáyé tí fi aṣọ rẹ hàn sí Ọba Eleguṣhi, tí ọba náà sì ṣàpèjúwe rẹ gẹ́gẹ́ bí akíkanjú tó ń gbé àṣà àti ìṣe ilẹ̀ Yorùbá lárugẹ káàkiri àgbáyé.
Wọ̀nyí ni bí eto abẹwo náà ṣe lọ sí
No comments:
Post a Comment