IṢẸ́-NLỌ! ETO ÌLERA ÌGBÀLÓDÉ: ÌJỌBA KWARA BẸ̀RẸ̀ ÀTÚNKỌ́ ỌSIBÍTÙ MAGAJI ARẸ N'ILU ILỌRIN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Tuesday, September 15, 2020

IṢẸ́-NLỌ! ETO ÌLERA ÌGBÀLÓDÉ: ÌJỌBA KWARA BẸ̀RẸ̀ ÀTÚNKỌ́ ỌSIBÍTÙ MAGAJI ARẸ N'ILU ILỌRIN


'Ìlera l'ọrọ̀' gẹ́gẹ́ báwọn ọjọgbọn ṣe máa ń sọ. Eto ìlera ṣe pàtàkì láwùjọ tó sì tún jé ọkàn pàtàkì lára àwọn nǹkan tó yẹ kí ìjọba aráàlú gbájúmọ́.

Bi ìgbáyé-gbádùn aráàlú ṣe jẹ́ Gómìnà AbdulRahman AbdulRazaq tipinlẹ Kwara lógún lo tún mú kó bẹ̀rẹ̀ àtúnkọ́ ọsibítù Magaji Arẹ to wá ń'ìjọba ìbílẹ̀ Ilọrin East, ìpínlẹ̀ náà. 

AWIKONKO gbọ́ pé lọ́nà ìgbàlódé tí yóò mú káwọn èèyàn wa ni ìlera pípé ni gbogbo igba ni ijọba AbdulRazaq fẹẹ kọ ọsibítù náà. 

Èyí ni bí iṣẹ ṣe ń lọ nibẹ:
he Kwara state Government has commenced the comprehensive rehabilitation and re-equipping of Magaji Are Primary Healthcare Centre in Ilorin East LGA with state of the art facilities as part of ongoing efforts by Governor AbdulRahman AbdulRazaq to provide an enabling environment for quality and affordable health care delivery to the citizens.No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI