Ọkàn pàtàkì ni Ọgbẹni Abiọdun Lawal jẹ́ lagboole oniroyin lorilẹ-ede Nàìjíríà, pàápàá ni ipinlẹ Ogun.
Lónìí ní ọkàn lára àwọn ọmọ rẹ ń ṣayẹyẹ ọjọ́ ìbí ọdún kẹjọ lókè eepẹ nínú oore Ọlọ́run.
A ń gbà á ladura pé ọmọ náà yóò dàgbà, yóò sì ṣe rere láyé nínú àlàáfíà àti ifọkanbalẹ ayérayé.
No comments:
Post a Comment