#ENDSARS: AWỌN ARAALU WỌ GAU LORI DUKIA IJỌBA AT'AWỌN ILEEṢẸ ALADANI TI WỌN JI GBE - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, October 29, 2020

#ENDSARS: AWỌN ARAALU WỌ GAU LORI DUKIA IJỌBA AT'AWỌN ILEEṢẸ ALADANI TI WỌN JI GBE

 
Gbogbo awọn to ji awọn ẹru ijọba ati t'awọn ileeṣẹ aladani to fi mọ awọn ounjẹ konilegbele kaakiri orilẹ-ede yii ni wọn ti wa ninu wahala nla bi ẹ ṣe n ka iroyin yii, ti igbagbọ si wa pe o ṣee ṣe ki gbogbo wọn fi ẹnu fẹra bi abẹbẹ.

Latigba ti iwọde ifẹhonu han ti ENDSARS ti gba ọna mi in yọ láwọn eeyan ti n ko awọn ẹru iranwọ fun isede konilegbele l'awọn ibi ti ijọba ko wọn pamọ si.

Bo tilẹ jẹ pe l'awọn ipinlẹ kọọkan lorilẹ-ede yii l'awọn to n ji dukia gbe ti bẹrẹ si i daa pada diẹ-diẹ, ṣugbọn sibẹ ọwọ palaba awọn kan ti n segi, ti wọn si ti wa lahamọ awọn agbofinro kaakiri Naijiria.
Eyi ni diẹ lara awọn tọwọ palaba wọn ti segiNo comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI