#ENDSARS: LẸ́YÌN ÌPÀDÉ PẸ̀LÚ ÀÀRẸ BUHARI, LAWAN, GBAJABIAMILA RAWỌ ẸBẸ S'AWỌN ỌMỌ NÀÌJÍRÍÀ LATI DAWỌ IFẸHONUHÀN DÚRÓ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Sunday, October 18, 2020

#ENDSARS: LẸ́YÌN ÌPÀDÉ PẸ̀LÚ ÀÀRẸ BUHARI, LAWAN, GBAJABIAMILA RAWỌ ẸBẸ S'AWỌN ỌMỌ NÀÌJÍRÍÀ LATI DAWỌ IFẸHONUHÀN DÚRÓ


Ààrẹ ilé igbimọ aṣofin, Ahmed Lawan àti abẹnugọn ilé igbimọ aṣojú-ṣòfin, Fẹmi Gbajabiamila tí rawọ ẹ̀bẹ̀  ọdọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọn ń fẹhonuhan lọ́wọ́lọ́wọ́ káàkiri ipinlẹ. 

Lẹ́yìn ìpàdé bonkẹlẹ tí àwọn méjèèjì ṣe pẹ̀lú Ààrẹ Buhari ni wọn sọ̀rọ̀ síta láti rawọ ẹ̀bẹ̀ náà pé kí wọn dawọ ifẹhonuhàn wọn dúró nítorí pé gbogbo nnkan ti wọn n beere fun làwọn yóò ṣe é. 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI