#ENDSARS: RÉDÍÒ 'SỌ̀RỌ̀ SÓKÈ' GUN ORÍ AFẸ́FẸ́ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Sunday, October 18, 2020

#ENDSARS: RÉDÍÒ 'SỌ̀RỌ̀ SÓKÈ' GUN ORÍ AFẸ́FẸ́


Bí ẹ ṣe ń ka ìròyìn yìí, rédíò 'SỌ̀RỌ̀ SÓKÈ' tí gun orí afẹ́fẹ́ láti máa fi tó gbogbo àwọn ọmọ Nàìjíríà àtàwọn èèyàn káàkiri àgbáyé létí nípa ohun tó ń lọ lórí ifẹhonuhàn #ENDSARS tó ń lásìkò yìí. 

Rédíò náà tó wà lórí ìkànni ayélujára SỌ̀RỌ̀ SÓKÈ là gbọ pé àwọn èèyàn ti bẹ̀rẹ̀ si í gbọ lásìkò yìí, níbi táwọn odò tí ń ṣàlàyé ìdí pàtàkì tí wọn ṣe ń fẹhonuhan síta. 

Owó tí kò dín ni ọgọ́rin mílíọ̀nù náírà là gbọ pé àwọn ẹlẹyinju àánú tí wọn nífẹ̀ẹ́ sì ohun tó ń ṣẹlẹ̀ yí tí dá láti fi rán àwọn ọdọ lọ́wọ́. 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI