ILEEṢẸ AARẸ TU AṢIRI NIPA AWỌN TO N JI OUNJẸ ATI DUKIA IJỌBA GBE - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, October 29, 2020

ILEEṢẸ AARẸ TU AṢIRI NIPA AWỌN TO N JI OUNJẸ ATI DUKIA IJỌBA GBE


Ileeṣẹ Aarẹ orilẹ-ede yii ti sọ pe ki i ṣe pe ebi lo n pa awọn araalu ti wọn n ji dukia at'awọn ounjẹ ijọba gbe lasiko yii, ati pe ki i ṣe pe inu lo n bi wọn.

O ni aaye aisi eto aabo to peye to ṣi silẹ l'awọn araalu lo anfaani rẹ lati fi ṣe nnkan to wu wọn lọkan, pẹlu ero wi pe ko sẹni to le mu wọn.

Ọgbẹni Fẹmi Adeṣina lo sọrọ yii sita nigba to n dahun ibeere lori amohunmaworan ti ileeṣẹ Channels.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI