NINU AYE! E WO PASITỌ TO N FA IRUN ABẸ AWỌN OBINRIN NINU ṢỌỌṢI - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Tuesday, October 13, 2020

NINU AYE! E WO PASITỌ TO N FA IRUN ABẸ AWỌN OBINRIN NINU ṢỌỌṢI

 
Pasitọ ti ẹ n wo yii lo tun tan kaakiri ikanni ayelujara lasiko yii, lori bi fido ibi to ti n fa irun abẹ awọn obinrin inu ṣoọọṣi ẹ, to si ni iṣẹ iyanu nla loun fi n ṣe e.

Orilẹ-ede Ghana lọhun la gbọ pe Pasitọ yii ti a ko ti i mọ orukọ ta a fi kọ iroyin yii tan wa, pupọ awọn ọmọ ijọ lo si ni, to maa n ṣe iṣẹ


idan to n pe ni iyanu fun wọn.

A gbọ pe awọn obinrin lo pọ ninu ṣọọṣi, iyẹn awọn ti wọn n wa iyanu ojiji.

Nibi ti wọn ni Pasitọ naa ti n sọrọ lo ti sọ fun gbogbo awọn to wa ni ṣọọṣi ẹ pe ki wọn yọ foonu wọn sita lati maa fi ya aworan nnkan toun n ṣe, ki iroyin ma ba a jade sita wi pe oun n bọ pata awọn obinrin.

Oriṣiriṣi l'awọn eeyan ti n sọ nipa pasitọ naa bayii.

 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI