Epe rabandẹ-rabandẹ làwọn ara agbegbe Ikot Ekpene tó wà ní ìpínlẹ̀ Akwa Ibom ń ṣẹ fún ọdọmọbinrin kan tí wọn loo ṣekú pá ìyá tó bí í lọmọ.
Kí í ṣe bo ṣe pá màmá náà dànù lo ń yà àwọn èèyàn agbègbè náà lẹ́nu bí kò ṣe bo tún ṣe dunbu ẹ bí ẹran ọdún Ileya.
Ọkàn lára àwọn tí ìṣẹ̀lẹ̀ náà wáyé lójú ẹ lo fi ranṣẹ síta pẹ̀lú àwọn fọto loriṣiriṣi. Ẹni náà lo sì jẹ ká mọ pe àdúgbò Urua Anan Road, Ikot Ekpene lo tí ṣẹlẹ̀
Bẹ́ẹ̀ lo fi ye wá pé àwọn ọlọ́pàá ni wọn padà wá palẹmọ òkú náà, tí wọn sì ni kò gbé e sórí de teṣan wọn.
Díẹ̀ rèé lára àwọn fọto:
No comments:
Post a Comment