O PARI! WỌ́N FI ẸSUN JÌBÌTÌ KAN KASNATY, GBAJUGBAJA SỌ̀RỌ̀SỌ̀RỌ̀ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Saturday, December 26, 2020

O PARI! WỌ́N FI ẸSUN JÌBÌTÌ KAN KASNATY, GBAJUGBAJA SỌ̀RỌ̀SỌ̀RỌ̀

Wọn ní Wòlíì Genesis lo kọ ọ niṣẹ


Obìnrin kan tí wọn pé orúkọ ẹ ní Bukọla Jesse lo fi. ẹ̀sùn jìbìtì kan Kasnaty laipẹ yìí nínú fọ́nrán kan tó ń lọ káàkiri orí ìkànnì ayélujára. 

Fọ́nrán náà rèé:


Gbogbo akitiyan láti gbọ ti ẹnu Kasnaty lórí ẹ̀sùn tí wọn fi kan án yìí ló ja si pàbó títí dasiko tá a kọ ìròyìn yìí tán. 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI