Laipẹ yii ni igbimọ fidihẹ ẹgbẹ oṣelu APC n'ipinlẹ Ogun yan awọn alaga fidihẹ ti yoo maa ṣakoso ẹgbẹ naa láwọn ijọba ibilẹ ogun to wa n'ipinlẹ naa.
AWIKONKO ti wa a mu orukọ gbogbo awọn ti wọn bura fun naa wa fun un yin lati mọ.
1. Abeokuta North : Alaaji Akeem Adeṣina Ṣobayọ
2. Abeokuta South: Henry Adetunji Fagbenro
3. Ijẹbu-Ode: Sikiru Adebayọ
4. Ọdeda: Saka Musulumi O.
5. Ijẹbu-East: Adebayọ Balogun
6. Ifo: Apostle Mathew Ọladele
7. Yewa North: SMA Akinyemi
8. Yewa South: Ọtunba Tunji Idowu
9. Ipokia: Onọrebu Taiye Zinsu Whepetoji
10. Ado Odo Ọta: David Ogundare
11. Imẹkọ Afọn: Alaaji Yaya Fadipẹ
12. Ewekoro: Ọnọrebu Biọdun Adelẹyẹ
13: Ijebu North: (Won ko ti i yan an)
14 Odogbolu: Oloye Ganiyu Ọdunlami
15. Ijebu North East: Wale Ọmọwunmi
16. Ọbafẹmi Owode: Oloye Idowu Olude
17: Ogun Waterside: Oloye Abiọla Logere
18 Ṣagamu: Ọgbẹni Rafiu Ọpalẹyẹ
19. Ikẹnnẹ: Jamiu Aṣimi
20 Rẹmọ North: Samson Ọdẹyẹmi
No comments:
Post a Comment