ẸGBẸẸGBẸRUN MILIỌNU ỌMỌ NAIJIRIA NI WỌN N DURO LATI DARAPỌ MỌ APC - GANDUJE SỌRỌ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, February 8, 2021

ẸGBẸẸGBẸRUN MILIỌNU ỌMỌ NAIJIRIA NI WỌN N DURO LATI DARAPỌ MỌ APC - GANDUJE SỌRỌ


Gomina ipinlẹ Kano, Abdullahi Umar Ganduje  ti sọ pe pupọ awọn ọmọ orilẹ-ede Naijiria ni wọn n duro lati darapọ mọ ẹgbẹ oṣelu
All Progressives Congress, iyẹn APC lasiko yii nitori ti wọn mọ pe ẹgbẹ alalubarika ni. 
 
Ẹgbẹ oṣelu APC lasiko yii ni wọn n tun iforukọsilẹ ṣe fun gbogbo awọn ọmọ ẹgbẹ wọn lati mọ awọn ojulowo ọmọ ẹgbẹ ṣaaju asiko eto ipolongo idibo ti yoo bẹrẹ l'ọdun to n bọ.
 
Ana ti i ṣe Sande ni Gomina Ganduje sọrọ yii nibi ti wọn ti fi iforukọsilẹ naa lelẹ n'ipinlẹ naa, to si ni gbogbo ọmọ Naijiria lo lanfaani lati darapọ.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI