Ẹ WO OJU AWỌN MẸ́TÀDÍNLỌ́GBỌ̀N TỌWỌ EFCC TẸ LÓRÍ ẸSUN JIBITI L'EKOO - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Saturday, April 17, 2021

Ẹ WO OJU AWỌN MẸ́TÀDÍNLỌ́GBỌ̀N TỌWỌ EFCC TẸ LÓRÍ ẸSUN JIBITI L'EKOO


Ko din ni mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n tọwọ awọn àjọ EFCC to n gbógun ti iwa ajẹbanu ati jibiti tẹ laipẹ yii lórí iwa jibiti l'Ekoo.

David Promise, Cyril Okodogbe, Taiwo Fẹmi, Jasa Oghenerwede Frank, Adesokan Ibrahim, Fẹmi Emmanuel Phillip, Jimọh Ọlayinka Alimi, Anene Dominic, Victor Damọla, Israel Attah, Alonge Oluwadamilare, Muhammadu Sani Garba, Luis Fred ati Adu Ọlaoluwa láwọn tọwọ tẹ naa.

Awọn yòókù ni Precious Utomi, Ọladosu Samuel, Andrew John, Ọlayiwọla Ojo, Ekong Samuel Enobong, Oluwakẹmi Ezekiel, Okewọle Ṣẹgun, Ọlawale Adekunle, Ajibade Idris Adeniyi, Imeobong-Odion Promise, Karaole Lateef, Rowland Emmanuel, ati Nelson Lucky.

Ọjọ kẹsan an oṣù yìí la gbọ pe ọwọ tẹ gbogbo wọn l'agbegbe Ayọbọ si Ipaja n'ipinlẹ Eko.

Mọto olowo nla loriṣiriṣi, kọmputa alagbeka ati foonu olowo nla loriṣiriṣi la gbọ pe wọn gba lọwọ wọn.

Fọto wọn ree:









No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI