Gbajugbaja Pasitọ Ṣẹnfuye ṣe ìgbéyàwó alarinrin pẹlú ìyàwó tuntun l'Abẹokuta - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Sunday, April 18, 2021

Gbajugbaja Pasitọ Ṣẹnfuye ṣe ìgbéyàwó alarinrin pẹlú ìyàwó tuntun l'Abẹokuta


Ẹsẹ ko gbero ninu ijọ Treasure House of God to wa ladugbo Quary nilu Abẹ́òkúta nigba ti gbajugbaja Pasitọ Ṣẹyẹ Ṣẹnfuye ṣe ìgbéyàwó alarinrin pẹlú iyawo tuntun to ṣẹṣẹ fẹ.

Inu oṣù kẹta odun 2019 ni Pasitọ Ṣẹyẹ Ṣẹnfuye padanu iyawo rẹ akọkọ, olóògbé Oluyẹmisi Ṣẹnfuye lẹyìn aisan ranpẹ.

Arabinrin Success Oluwaṣeun ni orúkọ iyawo tuntun ti Pasitọ Ṣẹnfuye ṣẹṣẹ gbe bayii, tàwọn èèyàn kaakiri si n ba a yọ.

Diẹ ree lara awọn fọto bi ayẹyẹ naa ṣe lọ:
No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI