AbdulRazaq b'awọn Ọba alaye meji, Ọlọfa t'ilu Ọffa ati Elese t'ilu Igbaja yọ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Sunday, May 9, 2021

AbdulRazaq b'awọn Ọba alaye meji, Ọlọfa t'ilu Ọffa ati Elese t'ilu Igbaja yọ


Lonii ni Ọlọfa t'ilu Ọffa, Ọba Muhammed Mufutau Gbadamọsi, Eṣuwoye keji  n ṣe ajọyọ ayẹyẹ ọdun mọkanla l'ori ipo, ti Ọba Ahmed Awuni Babalọla, Arepo kẹta naa si n ṣayẹyẹ ọdun mejilelọgbọn l'ori ipo pẹlu ayẹyẹ ọjọ ibi ọdun mọkanlelaadọrun-un l'oke eepẹ.
 
Gomina AbdulRahman AbdulRazaq n'igba to n b'awọn Ọba alaye naa ṣ'ajọyọ ṣapejuwe wọn gẹgẹ awọn ọba to n gba alaafia l'aaye, to si ni asiko wọn ti mu idagbasoke ti ko l'ẹlẹgbẹ wọ ipinlẹ naa.
 
 
Bẹẹ lo gb'adura ẹmi gigun ati alaafia fun wọn.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI