Nitori awọn mọto iṣẹlẹ pajawiri ti AbdulRazaq ra fawọn agbofinro, idaamu nla de bawọn ọdaran ni Kwara - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Wednesday, June 16, 2021

Nitori awọn mọto iṣẹlẹ pajawiri ti AbdulRazaq ra fawọn agbofinro, idaamu nla de bawọn ọdaran ni Kwara


Inu wahala ati idaamu nla ni gbogbo awọn ọdaran ti wọn wa kaakiri ipinlẹ Kwara wa lasiko ta a pari iroyin yii, lori bi wọn ṣe ni gomina AbdulRahman AbdulRazaq ti ṣetan lati ro gbogbo awọn agbofinro kaakiri ipinlẹ naa lagbara.

AWIKONKO gbọ pe ogunlọgọ awọn mọto tawọn agbofinro n lo lasiko iṣẹlẹ pajawiri ni AbdulRazaq ti ra kalẹ lati pin in f'awọn oṣiṣẹ eleto aabo patapata, ki eto aabo le tubọ kẹsẹjare.

Diẹ ree lara fọto awọn mọto naa, eyi ti a gbọ pe laipẹ yii ni wọn yoo pin in fawọn tọrọ kan:No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI