Awọn meji ti ẹ n wo yii la gbọ pe wọn ko niṣẹ meji ti wọn n ṣe ju ki wọn maa digun ja awọn eeyan lole ninu sunkẹrẹ-fakẹrẹ ọkọ ti wọn tun n pe ni gosilo l'Ekoo.
Laipẹ yii lọwọ awọn ọlọpaa RRS ti a mọ si Rapid Response Squad tẹ wọn lagbegbe Motorways si Chinatown, Ọjọta nipinlẹ Eko.
Panti ni wọn wa nigba ti a pari iroyin yii, nibi ti wọn ti n ran awọn ọlọpaa lọwọ ninu iwadii wọn.
No comments:
Post a Comment