Ìgbòho! Ẹ gbọ́ ohun ti ilé ẹjọ́ sọ nípa ìgbẹ́jọ́ tó n lọ lọ́wọ́ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, July 22, 2021

Ìgbòho! Ẹ gbọ́ ohun ti ilé ẹjọ́ sọ nípa ìgbẹ́jọ́ tó n lọ lọ́wọ́


Ilé ẹjọ́ to n gbọ ẹjọ ẹsun ti wọn fi kan Oloye Sunday Igboho lorilẹ-ede Benin ti sọ pe awọn nilo lati farabalẹ lati gbe ẹjọ naa yẹwo daadaa.

O ni ẹjọ naa ko ni le e pari lalẹ oni, Tọsidee, gẹgẹ ba a ṣe gbọ.

Aarọ ọla, ọjọ Ẹti, Furaidee ni igbẹjọ yoo tẹsiwaju, iyẹn bi ile ẹjọ ṣe sọ.

Agbejọ́rọ́ Oloye Sunday Adeyemo gẹgẹ bi a ṣe gbọ ṣàlàyé pe asiko ko tii to lati sọ̀rọ̀ lori igbẹ́jọ́ naa ṣugbọn oun gbagbọ́ pe didun lọ́san o so.

Agbejọ́rọ́ Ijoba naa ko ba awọ́n akọ́royin sọ́rọ̀.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI