
Ijọba ipinlẹ Kwara ti kọminu lori iku agba alẹnulọrọ nni, Oloogbe Alaaji Ahmẹd Jooda ti jade laye lọsẹ to kọja yii.
Gomina AbdulRahman AbdulRazaq sọ pe ojiji ni iroyin iku naa ba oun, eyi to lo ba oun lọkan jẹ gidi ni kete toun gbọ.
O ni akikanju to ja fitafita fun orilẹ-ede Naijiria ni Alaaji Jooda nigba aye ẹ, to si ba awọn mọlẹbi rẹ kẹdun.
No comments:
Post a Comment