Mi o ni kuna lori ọrọ eto aabo ki n to fijọba silẹ - Buhari - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Friday, August 20, 2021

Mi o ni kuna lori ọrọ eto aabo ki n to fijọba silẹ - Buhari


Aarẹ Muhammadu Buhari ti fi da gbogbo awọn ọmọ orilẹ-ede Naijriia loju wi pe oun ko ni gbe ijọba silẹ lai ri i wi pe ọrọ eto aabo apapọ kẹsẹjari.
 
Buhari sọ pe ko too to ọdun 2023, iyẹn asiko toun yoo ba fi gbe ijọba silẹ, oun yoo ti gbogun ti gbogbo awọn iṣoro ati ipenija to n dojukọ eto aabo orilẹ-ede yii.
 
Ọjọbọ, Tọside ana ni Aarẹ Buhari sọrọ yii nibi ipade ti wọn ṣe lori ọrọ eto aabo nile agbara ilu Abuja.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI