Ọ̀gá ọlọ́pàá orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ṣàbẹ̀wò si Kwara láti ṣèlérí ètò ààbò tó péye - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, September 16, 2021

Ọ̀gá ọlọ́pàá orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ṣàbẹ̀wò si Kwara láti ṣèlérí ètò ààbò tó péye


Ọga ọlọpaa patapata lorilẹ-ede yii, Usman Alkali Baba ti ṣeleri eto aabo to peye fun ijọba ipinlẹ Kwara ati gbogbo awọn araalu patapata, to si ni asiko naa ti to fun gbogbo eeyan lati maa sun orun asundọkan nipa didiju mejeeji.

Nibi abẹ ti Baba ṣe lọ sipinlẹ naa lana, Ọjọru, Wẹside lo ti ṣeleri yii, to si ni ileeṣẹ ọlọpaa yoo ṣe iranlọwọ to kun oju oṣuwọn lai ṣe ojusaaju.
 
Ṣaaju akoko yii ni Gomina AbdulRahman AbdulRazaq ti rawọ ẹbẹ   si ileeṣẹ ọlọpaa atawọn ileeṣẹ eleto aabo yooku fun iranlọwọ eto aabo to peye.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI