Ọ̀pọ̀ ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú PDP tún yawọ APC ní Kwara - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Tuesday, November 16, 2021

Ọ̀pọ̀ ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú PDP tún yawọ APC ní Kwara


Ko din ni ọgọrun-un kan ọmọ ẹgbẹ oṣelu People Democratic Party (PDP) ti wọn ti ya lọ sinu ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress (APC) nipinlẹ Kwara bayii.

Eyi tun waye lẹyin ọjọ kẹfa gbako tawọn ọmọ ẹgbẹ oṣelu PDP kan fẹgbẹ naa silẹ lọ APC.
 
AWIKONKO gbọ pe lara ohun tawọn eeyan naa n sọ ni pe ipa rere ti Gomina AbdulRahman AbdulRazaq fi lelẹ, ati awọn akanṣe iṣẹ to ti ṣe laaarin ọdun meji lo fa a tawọn fi lọ sinu ẹgbẹ APC.No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI