Ọmọbìnrin kan to pe orukọ rẹ ni Ọpẹyẹmi Adelakun lo ṣẹṣẹ gbe fọnran kan jade sori ikanni ayelujara bayii, nibi to ti n sọ pe aṣiri gbajugbaja sọrọ sọrọ nni, Kọlawọle Atanda Adejojo, ẹni tọpọ awọn eeyan mọ si Kasnaty Ṣuga ti tu.
Fọnran naa to tẹ AWIKONKO lọwọ ree
No comments:
Post a Comment