Wọ́n tún ti jí olùkọ́ gbé l'Ékìtì o - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, December 20, 2021

Wọ́n tún ti jí olùkọ́ gbé l'Ékìtì o


Iroyin yajoyajo to ṣẹṣẹ tẹ AWIKONKO lọwọ laipẹ yii ti fidi rẹ mulẹ wi pe awọn agbebọn kan ti ji ọkan lara awọn olukọ nipinlẹ Ekiti gbe lonii.

Olukọ naa, Arabinrin Awoniyi, la gbọ pe wọn jigbe loju ọna Ayebode Ekiti.

Ekunrẹrẹ iroyin naa n bọ laipẹ

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI