Ẹ wo ọyàn ràpàtà tí Wùnmí Ajíbóyè, ìyàwó Ṣẹ́gun Ògúngbè fi polówó ọjà lórí ayélujára - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, January 13, 2022

Ẹ wo ọyàn ràpàtà tí Wùnmí Ajíbóyè, ìyàwó Ṣẹ́gun Ògúngbè fi polówó ọjà lórí ayélujára


Latigba ti iyawo gbajugbaja oṣere tiata, Ṣẹgun Ogungbe, to filu Abẹokuta ṣe ibugbe, iyẹn Wunmi Ajiboye ti gbe fọto ọyan rẹ mejeeji rapata sori ikanni ayelujara ti Instagiraamu lawọn eeyan ti n sọ oriṣiriṣi.

Wunmi Ajiboye, ẹni to bẹrẹ iṣẹ tiata lọdọ Murphy Ray lo gbe fọto rẹ sita, to si loun ni ọmọ kekere-binrin titilai.

Fọto ọyan ti Wunmi, ọkan lara awọn iyawo Ṣẹgun Ogungbe ko sita yii lo wọ ọpọ awọn eeyan loju, ti wọn si n sọ pe amuumutan ni fun ọkọ rẹ.

Awọn kan tiẹ sọ pe ọyan yii ni Ṣẹgun ri lara rẹ, eyi to wọ ọ loju, to fi di pe o fẹẹ sile gẹgẹ bi iyawo rẹ.

Fọto naa ree:No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI